AYÉ Lyrics – Xhaka-Zulu
Singer: Xhaka-Zulu
Title: AYÉ
Hook
Ibí gbo gbo e re oké lọ rè bà
Ibí gbo gbo e rè oké lọ rè bà
Ibí gbo gbo e rè oké lọ rè bà
Ibí gbo gbo e rè oké lọ rè bá
Bridge
Bó ṣe ayé rè o ma kù
Bó ṣe ayé rè o ma kú
Kilo tun wá ku abeg you make you do good oh
Ire l’ope ika òpe ọlọrun o bímọ ẹsan lóbí
Ayé l’ọja òrun ní ilé, ma gbádùn ọjà gbà gbé ilé
Ayé! Ayé!! Ayé!!! Ayé!!!!
Asán ma l’ayé
Ayé! Ayé!!
Aye toto, Aye akamara
Ọpọ nínú ayé, nínú ayé tiwọn tí jẹ ma ayé
Ẹdà mi ma sùn ma mọ jẹ kiwọn jẹ mi mọ ayé
Ayé! Ayé!! Ayé!!! Ayé!!!!
Ayé kan lo wa
Ayé! Ayé!! Ayé!!!
Ka sha ma jẹ àiyé
Ayé! ayé!! ayé!!! ayé!!!!
Ọrẹ nínú ayé
Ajé! Ajé!! Ajé!!! Ajé!!!
La fí gbádùn ayé
Ọrẹ mí àní ma ṣe ahun , ọmọ a jẹ ìgbín jẹ ikarahun
To ba ni l’ọwọ koni ṣe ahun, a fi àìní lọwọ l’ofe jọ ahun
Ibadan ti o mọ ko jọ layipo, ijapa ti o mọ o jọ yanibo
Àtòrì mó l’ayé bi a fi sí waju a fi sí ẹyin
I don’t know how you play
But I’m ready to play how you wan play
I let them know the xharks don’t play
I’ve really got to show the xharks don’t play
See, this life if you do good you go see good so do good
See this life if you do good you go see good so do good
Korin
Ayé! Ayé!! Ayé!!! Ayé!!!!
Asán ma l’ayé
Ayé! Ayé!!
Aye toto, Aye akamara
Ọpọ nínú ayé, nínú ayé tiwọn tí jẹ ma ayé
Ẹdà mi ma sùn ma mọ jẹ kiwọn jẹ mi mọ ayé
Ayé! Ayé!! Ayé!!! Ayé!!!!
Ayé kan lo wa
Ayé! Ayé!! Ayé!!! Ayé!!!!
Ka sha ma jẹ àiyé
Ayé! ayé!! ayé!!! ayé!!!!
Ọrẹ nínú ayé
Ajé! Ajé!! Ajé!!! Ajé!!!
La fí gbádùn ayé
Hook
Ibí gbo gbo e re oké lọ rè ba
Ibí gbo gbo e re oké lọ rè ba
Ibí gbo gbo e re oké lọ rè ba
Ibí gbo gbo e re oké lọ rè ba
Ayé! Ayé!! Ayé!!! Ayé!!!!
Asán ma l’ayé
Ayé! Ayé!!
Aye toto, Aye akamara
Ọpọ nínú ayé, nínú ayé tiwọn tí jẹ ma ayé
Ẹdà mi ma sùn ma mọ jẹ kiwọn jẹ mi mọ ayé
Ayé! Ayé!! Ayé!!! Ayé!!!!
Ayé kan lo wa
Ayé! Ayé!! Ayé!!! Ayé!!!
Ka sha ma jẹ àiyé
Ayé! ayé!! ayé!!! ayé!!!!
Ọrẹ nínú ayé
Ajé! Ajé!! Ajé!!! Ajé!!!
La fí gbádùn ayé
Find more lyrics at lyrics.jspinyin.net
You can purchase their music thru Disclosure: As an Amazon Associate and an Apple Partner, we earn from qualifying purchases
Other Popular Songs:
Suero King Lyrics - DESORDEN
Do or Die - Wa Da Da Dang
AYÉ – English Translation
Hook
Lazing it’s the hour
Leither of the pasture crash
Leither of the pasture crash
Least of Ab’e How’s
Bridge
His life was not yet left
His life will not die
Known also the remaining Abeg You Make You do good oh
Hailmone tokens the reason for God ‘
The world of the world is a market in house, bankruptcy
Chance! Chance!! Chance!!! Chance!!!!
Eternal duration
Chance! Chance!!
The world of the world, Okomara’s Site
Many in the world, in their lives, world
My coppent will lie sleep, not to my life
Chance! Chance!! Chance!!! Chance!!!!
There are a world
Chance! Chance!! Chance!!!
Read Shipping Show
Chance! chance!! chance!!! chance!!!!
Friends in the world
Witchcraft! Witchcraft!! Witchcraft!!! Witchcraft!!!
La enjoy life
My friend even left the heart, a mock is a slaughter
If it is not the heart, you will be able to take place together the heart
You know that you know does not occur in the time of the torture turtle together
The Shape like we were to be available to you
I dn’t know how you play
BUT I’M Ready to Play How You Wand Play
I LET Them Know The Xharks Don’st Play
I’ve Really Got to Show the Xharks Don’st Play
See, this Life if you do good you go and Good So Good So Good
See YIIS Life If You Do Good You Go Good You BOOD Connouncing
Sing
Chance! Chance!! Chance!!! Chance!!!!
Eternal duration
Chance! Chance!!
The world of the world, Okomara’s Site
Many in the world, in their lives, world
My coppent will lie sleep, not to my life
Chance! Chance!! Chance!!! Chance!!!!
There are a world
Chance! Chance!! Chance!!! Chance!!!!
Read Shipping Show
Chance! chance!! chance!!! chance!!!!
Friends in the world
Witchcraft! Witchcraft!! Witchcraft!!! Witchcraft!!!
La enjoy life
Hook
Leither of the earth this hour
Leither of the earth this hour
Leither of the earth this hour
Leither of the earth this hour
Chance! Chance!! Chance!!! Chance!!!!
Eternal duration
Chance! Chance!!
The world of the world, Okomara’s Site
Many in the world, in their lives, world
My coppent will lie sleep, not to my life
Chance! Chance!! Chance!!! Chance!!!!
There are a world
Chance! Chance!! Chance!!! Chance!!!
Read Shipping Show
Chance! chance!! chance!!! chance!!!!
Friends in the world
Witchcraft! Witchcraft!! Witchcraft!!! Witchcraft!!!
La enjoy life
Find more lyrics at lyrics.jspinyin.net
Lyrics Xhaka-Zulu – AYÉ
Kindly like and share our content. Please follow our site to get the latest lyrics for all songs.
We don’t provide any MP3 Download, please support the artist by purchasing their music 🙂
You can purchase their music thru Disclosure: As an Amazon Associate and an Apple Partner, we earn from qualifying purchases